Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 6:20 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹbọ tí àwọn ọmọ Aaroni yóo máa rú, ní ọjọ́ tí wọ́n bá fi wọ́n joyè alufaa nìyí: Ìdámẹ́wàá ìwọ̀n efa ìyẹ̀fun tí ó kúnná dáradára, gẹ́gẹ́ bí ẹbọ ohun jíjẹ, ìdajì rẹ̀ ní òwúrọ̀, ìdajì tí ó kù ní àṣáálẹ́.

Ka pipe ipin Lefitiku 6

Wo Lefitiku 6:20 ni o tọ