Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 6:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn kò gbọdọ̀ fi ìwúkàrà sí i, bí wọ́n bá fi ṣe burẹdi, èmi ni mo fún wọn, gẹ́gẹ́ bí ìpín tiwọn ninu ẹbọ sísun mi; ó jẹ́ ohun mímọ́ jùlọ, gẹ́gẹ́ bí ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀ ati ti ìmúkúrò ẹ̀bi.

Ka pipe ipin Lefitiku 6

Wo Lefitiku 6:17 ni o tọ