Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 5:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí ó gbé ìyẹ̀fun náà tọ alufaa wá, kí alufaa bu ẹ̀kúnwọ́ kan ninu rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ẹbọ ìrántí, kí ó sì fi rú ẹbọ sísun lórí pẹpẹ sí OLUWA, ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀ ni.

Ka pipe ipin Lefitiku 5

Wo Lefitiku 5:12 ni o tọ