Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 4:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí ó gbé ọwọ́ lórí ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀ yìí, kí ó sì pa á fún ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀ níbi tí wọ́n ti ń pa ẹran tí wọ́n bá fẹ́ fi rú ẹbọ sísun.

Ka pipe ipin Lefitiku 4

Wo Lefitiku 4:33 ni o tọ