Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 4:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Yóo yọ gbogbo ọ̀rá ewúrẹ́ náà, bí wọ́n ti ń yọ ọ̀rá ẹran tí wọ́n bá fi rú ẹbọ alaafia, alufaa yóo sì sun ún níná lórí pẹpẹ gẹ́gẹ́ bí ẹbọ olóòórùn dídùn sí OLUWA. Alufaa yóo ṣe ètùtù fún un, OLUWA yóo sì dáríjì í.

Ka pipe ipin Lefitiku 4

Wo Lefitiku 4:31 ni o tọ