Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 4:3 BIBELI MIMỌ (BM)

“Bí ó bá jẹ́ alufaa tí a fi àmì òróró yàn ni ó ṣèèṣì dẹ́ṣẹ̀, tí ó sì kó ẹ̀bi bá àwọn eniyan, kí ó fi ọ̀dọ́ akọ mààlúù rú ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀ níwájú OLUWA, fún ẹ̀ṣẹ̀ tí ó dá.

Ka pipe ipin Lefitiku 4

Wo Lefitiku 4:3 ni o tọ