Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 4:28 BIBELI MIMỌ (BM)

lẹ́yìn tí wọ́n bá fi ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ tí ó dá hàn án, yóo mú abo ewúrẹ́ tí kò ní àbààwọ́n wá, yóo fi rúbọ fún ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀ tí ó ti dá.

Ka pipe ipin Lefitiku 4

Wo Lefitiku 4:28 ni o tọ