Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 3:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Yóo sì yọ àwọn nǹkan wọnyi ninu rẹ̀ láti fi rú ẹbọ tí a fi iná sun sí OLUWA: gbogbo ọ̀rá tí ó bo àwọn nǹkan inú rẹ̀, ati ọ̀rá tí ó bo ìfun rẹ̀,

Ka pipe ipin Lefitiku 3

Wo Lefitiku 3:14 ni o tọ