Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 27:9 BIBELI MIMỌ (BM)

“Bí ó bá jẹ́ pé ẹran ni eniyan jẹ́jẹ̀ẹ́ láti mú wá, gẹ́gẹ́ bí ọrẹ ẹbọ sí OLUWA, gbogbo irú nǹkan bẹ́ẹ̀ tí eniyan bá fún OLUWA jẹ́ mímọ́.

Ka pipe ipin Lefitiku 27

Wo Lefitiku 27:9 ni o tọ