Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 27:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ó bá jẹ́ ọmọ oṣù kan sí ọmọ ọdún marun-un, tí ó sì jẹ́ ọkunrin, yóo san ìwọ̀n ṣekeli fadaka marun-un, bí ó bá jẹ́ obinrin, yóo san ìwọ̀n ṣekeli fadaka mẹta.

Ka pipe ipin Lefitiku 27

Wo Lefitiku 27:6 ni o tọ