Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 27:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Darandaran náà kò gbọdọ̀ bèèrè bóyá ó dára tabi kò dára, bẹ́ẹ̀ ni kò sì gbọdọ̀ pààrọ̀ rẹ̀. Bí ó bá fẹ́ pààrọ̀ rẹ̀, ati èyí tí ó fi pààrọ̀ ati èyí tí ó pààrọ̀, mejeeji jẹ́ mímọ́ fún OLUWA, ẹnikẹ́ni kò sì gbọdọ̀ rà á pada.”

Ka pipe ipin Lefitiku 27

Wo Lefitiku 27:33 ni o tọ