Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 26:25 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo fi ogun ko yín, tí yóo gbẹ̀san nítorí majẹmu mi. Bí ẹ bá sì kó ara yín jọ sinu àwọn ìlú olódi yín, n óo rán àjàkálẹ̀ àrùn sí ààrin yín, n óo sì fi yín lé àwọn ọ̀tá yín lọ́wọ́.

Ka pipe ipin Lefitiku 26

Wo Lefitiku 26:25 ni o tọ