Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 26:16 BIBELI MIMỌ (BM)

ohun tí n óo ṣe sí yín nìyí: n óo rán ìbẹ̀rù si yín lójijì, àìsàn burúkú ati ibà tí ń bani lójú jẹ́ yóo bẹ́ sílẹ̀ láàrin yín, ẹ óo sì bẹ̀rẹ̀ sí kú sára. Bí ẹ bá gbin ohun ọ̀gbìn, òfò ni yóo jásí, nítorí pé àwọn ọ̀tá yín ni yóo jẹ ẹ́.

Ka pipe ipin Lefitiku 26

Wo Lefitiku 26:16 ni o tọ