Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 25:53 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkunrin tí ó ta ara rẹ̀ yìí yóo dàbí iranṣẹ tí à ń gbà lọdọọdun sí ẹni tí ó rà á; ẹni tí ó rà á kò gbọdọ̀ fi ọwọ́ líle mú un lójú rẹ̀.

Ka pipe ipin Lefitiku 25

Wo Lefitiku 25:53 ni o tọ