Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 25:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ohunkohun tí ó bá dá hù fún ara rẹ̀ ninu oko yín, ẹ kò gbọdọ̀ kórè rẹ̀. Ẹ kò gbọdọ̀ kórè èso tí ó bá so ninu ọgbà àjàrà yín tí ẹ kò tọ́jú. Ọdún náà gbọdọ̀ jẹ́ ọdún ìsinmi fún ilẹ̀.

Ka pipe ipin Lefitiku 25

Wo Lefitiku 25:5 ni o tọ