Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 25:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ẹnikẹ́ni kò gbọdọ̀ ta ilẹ̀ tí ó jẹ́ ti gbogbogbòò, tí ó wà ní àyíká àwọn ìlú wọn, nítorí pé, ogún tiwọn nìyí títí ayérayé.

Ka pipe ipin Lefitiku 25

Wo Lefitiku 25:34 ni o tọ