Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 25:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn bí kò bá ní agbára tó láti ra ilẹ̀ náà pada fúnra rẹ̀, ilẹ̀ náà yóo wà ní ọwọ́ ẹni tí ó rà á lọ́wọ́ rẹ̀ títí di ọdún jubili. Ní ọdún jubili, ẹni tí ó ra ilẹ̀ náà yóo dá a pada, ẹni tí ó ni ín yóo sì pada sórí ilẹ̀ rẹ̀.

Ka pipe ipin Lefitiku 25

Wo Lefitiku 25:28 ni o tọ