Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 25:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ẹ bá gbin ohun ọ̀gbìn ní ọdún kẹjọ, ẹ óo tún máa rí àwọn èso tí ó ti wà ní ìpamọ́ jẹ títí tí yóo fi di ọdún kẹsan-an, tí ilẹ̀ yóo tún mú èso rẹ̀ jáde wá, àwọn èso ti àtẹ̀yìnwá ni ẹ óo máa jẹ.

Ka pipe ipin Lefitiku 25

Wo Lefitiku 25:22 ni o tọ