Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 25:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Iye ọdún tí ó bá ti rékọjá lẹ́yìn ọdún jubili ni ẹ óo máa wò ra ilẹ̀ lọ́wọ́ aládùúgbò yín, iye ọdún tí ẹ bá fi lè gbin ohun ọ̀gbìn sórí ilẹ̀ kan kí ọdún jubili tó dé ni òun náà yóo máa wò láti tà á fun yín.

Ka pipe ipin Lefitiku 25

Wo Lefitiku 25:15 ni o tọ