Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 25:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé, ọdún jubili ni yóo máa jẹ́ fun yín, yóo jẹ́ ọdún mímọ́ fun yín, ninu oko ni ẹ óo ti máa jẹ ohun tí ó bá so.

Ka pipe ipin Lefitiku 25

Wo Lefitiku 25:12 ni o tọ