Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 23:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn, ẹ óo máa rú ẹbọ sísun sí OLUWA fún ọjọ́ meje náà, ọjọ́ àpèjọ mímọ́ ni ọjọ́ keje yóo jẹ́, ẹ kò gbọdọ̀ ṣe iṣẹ́ tí ó lágbára.”

Ka pipe ipin Lefitiku 23

Wo Lefitiku 23:8 ni o tọ