Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 23:34 BIBELI MIMỌ (BM)

pé kí ó sọ fún àwọn eniyan Israẹli pé, “Láti ọjọ́ kẹẹdogun oṣù keje lọ, ẹ óo ṣe àjọ̀dún Àgọ́ fún OLUWA; ọjọ́ meje ni ẹ óo fi ṣe é.

Ka pipe ipin Lefitiku 23

Wo Lefitiku 23:34 ni o tọ