Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 23:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ pe àpèjẹ mímọ́ ní ọjọ́ náà; ẹ kò sì gbọdọ̀ ṣe iṣẹ́ líle kankan ní ọjọ́ náà. Ìlànà ni èyí yóo jẹ́ fún arọmọdọmọ yín ní gbogbo ilẹ̀ yín títí lae.

Ka pipe ipin Lefitiku 23

Wo Lefitiku 23:21 ni o tọ