Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 23:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ kò gbọdọ̀ jẹ burẹdi tabi ọkà, kì báà jẹ́ ọkà yíyan tabi tútù títí di ọjọ́ yìí, tí ẹ óo fi mú ẹbọ Ọlọrun yín wá, ìlànà ni èyí yóo jẹ́ fún ìrandíran yín, ní gbogbo ilẹ̀ yín.

Ka pipe ipin Lefitiku 23

Wo Lefitiku 23:14 ni o tọ