Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 22:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ níláti jẹ gbogbo rẹ̀ tán ní ọjọ́ kan náà, kò gbọdọ̀ kù di òwúrọ̀ ọjọ́ keji. Èmi ni OLUWA.

Ka pipe ipin Lefitiku 22

Wo Lefitiku 22:30 ni o tọ