Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 22:27 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nígbà tí mààlúù, aguntan, tabi ewúrẹ́ bá bímọ, ẹ fi ọmọ náà sílẹ̀ pẹlu rẹ̀ fún ọjọ́ meje, láti ọjọ́ kẹjọ lọ ni ó tó lè jẹ́ ìtẹ́wọ́gbà fún ẹbọ sísun sí OLUWA.

Ka pipe ipin Lefitiku 22

Wo Lefitiku 22:27 ni o tọ