Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 22:2 BIBELI MIMỌ (BM)

“Sọ fún Aaroni ati àwọn ọmọkunrin rẹ̀ pé, kí wọ́n máa fi tọ̀wọ̀tọ̀wọ̀ lo àwọn nǹkan mímọ́ tí àwọn eniyan Israẹli yà sọ́tọ̀ fún mi, kí wọ́n má baà ba orúkọ mímọ́ mi jẹ́. Èmi ni OLUWA.

Ka pipe ipin Lefitiku 22

Wo Lefitiku 22:2 ni o tọ