Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 22:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn bí alufaa bá fi owó ra ẹrú fún ara rẹ̀, ẹrú náà lè jẹ ninu àwọn ohun mímọ́ náà. Àwọn ọmọ tí ẹrú náà bá sì bí ninu ilé alufaa náà lè jẹ ninu oúnjẹ náà pẹlu.

Ka pipe ipin Lefitiku 22

Wo Lefitiku 22:11 ni o tọ