Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 21:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Èyíkéyìí ninu arọmọdọmọ Aaroni, alufaa tí ó bá ti ní àbùkù kan lára kò gbọdọ̀ súnmọ́ ibi pẹpẹ láti rú ẹbọ sísun sí èmi OLUWA, níwọ̀n ìgbà tí ó bá ṣì ní àbùkù lára, kò gbọdọ̀ súnmọ́ ibi pẹpẹ láti rú ẹbọ ohun jíjẹ sí Ọlọrun rẹ̀.

Ka pipe ipin Lefitiku 21

Wo Lefitiku 21:21 ni o tọ