Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 21:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé, ẹnikẹ́ni tí ó bá ní àbùkù kò gbọdọ̀ súnmọ́ ibi pẹpẹ láti rú ẹbọ, kì báà jẹ́ afọ́jú, tabi arọ, ẹni tí ijamba bá bà lójú jẹ́, tabi tí apá tabi ẹsẹ̀ rẹ̀ kan gùn ju ekeji lọ,

Ka pipe ipin Lefitiku 21

Wo Lefitiku 21:18 ni o tọ