Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 21:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Kò gbọdọ̀ fi opó ṣe aya tabi obinrin tí ó kọ ọkọ rẹ̀ sílẹ̀, tabi obinrin tí ó ti mọ ọkunrin, tabi aṣẹ́wó; kò gbọdọ̀ fẹ́ èyíkéyìí ninu wọn. Obinrin tí kò tíì mọ ọkunrin rí ni kí ó fẹ́ láàrin àwọn eniyan rẹ̀.

Ka pipe ipin Lefitiku 21

Wo Lefitiku 21:14 ni o tọ