Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 21:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Kò sì gbọdọ̀ jáde kúrò ninu ibi mímọ́ náà, tabi kí ó sọ ibi mímọ́ Ọlọrun rẹ̀ di aláìmọ́, nítorí pé, òróró ìyàsímímọ́ Ọlọrun rẹ̀ wà lórí rẹ̀. Èmi ni OLUWA.

Ka pipe ipin Lefitiku 21

Wo Lefitiku 21:12 ni o tọ