Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 20:9 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹnikẹ́ni tí ó bá ṣépè lé baba tabi ìyá rẹ̀, pípa ni kí wọ́n pa á. Ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ yóo wà lórí ara rẹ̀ nítorí pé ó ṣépè lé baba tabi ìyá rẹ̀.

Ka pipe ipin Lefitiku 20

Wo Lefitiku 20:9 ni o tọ