Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 20:6 BIBELI MIMỌ (BM)

“Bí ẹnìkan bá ń lọ ṣe àyẹ̀wò lọ́dọ̀ àwọn abókùúsọ̀rọ̀, tabi àwọn oṣó, tí ó sì ń tọ̀ wọ́n lẹ́yìn, n óo kẹ̀yìn sí olúwarẹ̀, n óo sì yọ ọ́ kúrò láàrin àwọn eniyan rẹ̀.

Ka pipe ipin Lefitiku 20

Wo Lefitiku 20:6 ni o tọ