Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 20:27 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹnikẹ́ni tí ó bá jẹ́ abókùúsọ̀rọ̀ tabi oṣó, pípa ni kí ẹ pa á; ẹ sọ wọ́n ní òkúta pa ni, ẹ̀jẹ̀ wọn yóo sì wà lórí ara wọn.”

Ka pipe ipin Lefitiku 20

Wo Lefitiku 20:27 ni o tọ