Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 20:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ẹnìkan bá bá aya arakunrin baba rẹ̀ lòpọ̀, ohun ìtìjú ni ó ṣe sí arakunrin baba rẹ̀. Àwọn mejeeji yóo sì fi orí ara wọn ru ẹ̀bi ẹ̀ṣẹ̀ wọn, wọn yóo kú láì bímọ.

Ka pipe ipin Lefitiku 20

Wo Lefitiku 20:20 ni o tọ