Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 2:5 BIBELI MIMỌ (BM)

“Bí ó bá jẹ́ pé ohun jíjẹ tí a yan lórí ààrò ni ó fi rúbọ, kí ó jẹ́ èyí tí ìyẹ̀fun rẹ̀ kúnná dáradára, tí a fi òróró pò, kí ó má sì ní ìwúkàrà ninu.

Ka pipe ipin Lefitiku 2

Wo Lefitiku 2:5 ni o tọ