Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 2:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí ó gbé e tọ àwọn ọmọ Aaroni, alufaa, lọ, kí alufaa náà bu ẹ̀kúnwọ́ kan ninu ìyẹ̀fun náà, pẹlu òróró ati turari tí ó wà lórí rẹ̀. Ẹ̀kúnwọ́ kan yìí ni alufaa yóo sun fún ìrántí, ẹbọ olóòórùn dídùn, tí a fi iná sun sí OLUWA.

Ka pipe ipin Lefitiku 2

Wo Lefitiku 2:2 ni o tọ