Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 19:35 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹ kò gbọdọ̀ ṣèrú nígbà tí ẹ bá ń wọn nǹkan fún eniyan, kì báà jẹ́ ohun tí a fi ọ̀pá wọ̀n, tabi ohun tí a fi òṣùnwọ̀n wọ̀n, tabi ohun tí a kà,

Ka pipe ipin Lefitiku 19

Wo Lefitiku 19:35 ni o tọ