Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 19:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Alufaa yóo fi àgbò ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀bi náà ṣe ètùtù fún un níwájú OLUWA nítorí ẹ̀ṣẹ̀ tí ó dá, OLUWA yóo sì dárí ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ jì í.

Ka pipe ipin Lefitiku 19

Wo Lefitiku 19:22 ni o tọ