Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 19:19 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹ gbọdọ̀ pa àwọn ìlànà mi mọ́, ẹ kò gbọdọ̀ jẹ́ kí oríṣìí meji ninu àwọn ohun ọ̀sìn yín gun ara wọn, ẹ kò gbọdọ̀ gbin oríṣìí èso meji sinu oko kan náà, bẹ́ẹ̀ ni ẹ kò gbọdọ̀ fi oríṣìí aṣọ meji dá ẹ̀wù kan ṣoṣo.

Ka pipe ipin Lefitiku 19

Wo Lefitiku 19:19 ni o tọ