Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 18:8 BIBELI MIMỌ (BM)

O kò gbọdọ̀ bá aya baba rẹ lòpọ̀ nítorí pé bí ẹni ń tú baba ẹni síhòòhò ni.

Ka pipe ipin Lefitiku 18

Wo Lefitiku 18:8 ni o tọ