Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 18:30 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nítorí náà, ẹ pa àwọn àṣẹ mi mọ́, kí ẹ má sì ṣe èyíkéyìí ninu àwọn ohun ìríra wọnyi, tí àwọn tí wọ́n ṣáájú yín ṣe, kí ẹ má fi wọ́n ba ara yín jẹ́. Èmi ni OLUWA Ọlọrun yín.”

Ka pipe ipin Lefitiku 18

Wo Lefitiku 18:30 ni o tọ