Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 18:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ kò gbọdọ̀ ṣe bí wọ́n ti ń ṣe ní ilẹ̀ Ijipti, níbi tí ẹ ti gbé rí, bẹ́ẹ̀ ni ẹ kò gbọdọ̀ ṣe bí wọ́n ti ń ṣe ní ilẹ̀ Kenaani níbi tí mò ń ko yín lọ. Ẹ kò gbọdọ̀ tẹ̀lé ìlànà wọn.

Ka pipe ipin Lefitiku 18

Wo Lefitiku 18:3 ni o tọ