Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 17:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Alufaa yóo sì máa wọ́n ẹ̀jẹ̀ wọn sí ara pẹpẹ OLUWA lẹ́nu ọ̀nà Àgọ́ Àjọ, yóo sì sun ọ̀rá wọn bí ẹbọ sísun olóòórùn dídùn sí OLUWA.

Ka pipe ipin Lefitiku 17

Wo Lefitiku 17:6 ni o tọ