Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 16:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Aaroni yóo fa ẹran tí gègé OLUWA bá mú kalẹ̀ níwájú OLUWA, yóo sì fi rú ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀.

Ka pipe ipin Lefitiku 16

Wo Lefitiku 16:9 ni o tọ