Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 16:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Òbúkọ náà yóo sì fi orí rẹ̀ ru gbogbo àìṣedéédé wọn, títí tí ẹni náà yóo fi fà á dé ibi tí eniyan kì í gbé, ibẹ̀ ni yóo ti sọ ọ́ sílẹ̀ kí ó lè wọ inú aṣálẹ̀ lọ.

Ka pipe ipin Lefitiku 16

Wo Lefitiku 16:22 ni o tọ