Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 16:2 BIBELI MIMỌ (BM)

“Sọ fún Aaroni arakunrin rẹ pé kí ó má ṣe máa wọ ibi mímọ́ jùlọ, tí ó wà lẹ́yìn aṣọ títa, níwájú ìtẹ́ àánú tí ó wà lórí àpótí ẹ̀rí nígbà gbogbo, kí ó má baà kú; nítorí pé n óo fi ara hàn ninu ìkùukùu, lórí ìtẹ́ àánú.

Ka pipe ipin Lefitiku 16

Wo Lefitiku 16:2 ni o tọ