Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 16:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, yóo mú ẹ̀yinná láti orí pẹpẹ tí ó wà níwájú OLUWA sinu àwo turari, yóo sì bu turari olóòórùn dídùn tí wọ́n gún, ẹ̀kúnwọ́ meji, yóo sì gbé e lọ sinu ibi tí aṣọ ìbòjú wà.

Ka pipe ipin Lefitiku 16

Wo Lefitiku 16:12 ni o tọ