Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 15:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Èyí sì ni òfin tí ó jẹmọ́ àìmọ́ rẹ̀, nítorí nǹkan tí ó ti ara rẹ̀ jáde; kì báà jẹ́ pé ó ń dà lọ́wọ́ lọ́wọ́, tabi ó ti dà tán, nǹkan tí ó dà yìí jẹ́ àìmọ́ lára rẹ̀.

Ka pipe ipin Lefitiku 15

Wo Lefitiku 15:3 ni o tọ